ẹ̀tọ́ọ̀ mi si ìpamọ́n

gbogbo ọmọ Nàìjíríà ni o ní ẹ̀tọ́ sí ààbò ìpamọ́; ìpamọ́ ilé, ìpamọ́ gbogbo ìbánisọ̀rọ̀ bí lẹ́tà, ẹ̀rọ ìbánisọ̀rọ̀, ẹ̀rọ ìfìweránṣẹ́ tẹligíráfù.